Wikipedia
yowiki
https://yo.wikipedia.org/wiki/Oj%C3%BAew%C3%A9_%C3%80k%E1%BB%8D%CC%81k%E1%BB%8D%CC%81
MediaWiki 1.39.0-wmf.25
first-letter
Amóhùnmáwòrán
Pàtàkì
Ọ̀rọ̀
Oníṣe
Ọ̀rọ̀ oníṣe
Wikipedia
Ọ̀rọ̀ Wikipedia
Fáìlì
Ọ̀rọ̀ fáìlì
MediaWiki
Ọ̀rọ̀ mediaWiki
Àdàkọ
Ọ̀rọ̀ àdàkọ
Ìrànlọ́wọ́
Ọ̀rọ̀ ìrànlọ́wọ́
Ẹ̀ka
Ọ̀rọ̀ ẹ̀ka
Èbúté
Ọ̀rọ̀ èbúté
Ìwé
Ọ̀rọ̀ ìwé
TimedText
TimedText talk
Module
Module talk
Gadget
Gadget talk
Gadget definition
Gadget definition talk
Toyosi Akerele-Ogunsiji
0
67563
558474
558449
2022-08-20T12:05:51Z
Enitanade
24674
Atunkọ
wikitext
text/x-wiki
{{Infobox person|name=Toyosi Akerele-Ogunsiji|image=Toyosi Akerele.jpg|birth_name=Toyosi Akerele|birth_date={{Birth date and age|1983|11|08|df=yes}}|birth_place=[[Lagos State]], [[Nigeria]]|occupation=onisowo iṣowo|website={{URL|www.toyosi.ng}}}}
'''Toyosi Akerele-Ogunsiji''' (wọ́n bí Oluwatoyosi Akerele, ní ọjọ́ kẹ́jo oṣù kọkànlá ọdún 1983) jẹ́ alákòóso àwọn olókoòwò-aládáni ti ìlu Nàìjírííà àti ọnímọ̀ nípa ìdàgbàsóke àwọn ènìyàn tí ọwọ́ ìja rẹ̀ lọ jákèjádò okoòwò-aládáni, ètò-ẹ̀kọ́, ìdàgbàsókè àwọn ọ̀dọ́ àti ìdarí ìlú. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti alákòóso àgbà ti Rise Networks, tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ aládàáni àti tìjọba tí ó ń ṣètò ìrànlọ́wọ́ owó fún àwọn ọ̀dọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjírííà.[1]
==Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́==
Wọ́n bí Akerele-Ogunsiji sínú ẹbí James Ayodele àti Felicia Mopelola Akerele ní ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjírííà. Ó lọ si ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Ebun Oluwa Nursery and Primary School, ní Ọrẹgun ní ìpínlẹ̀ Èkó láti bẹ̀ ni ó ti darí sí Lagos State Model College Kankon ní Badagry, ní ìpínlẹ̀ Èkó fún abala kínní ẹ̀kọ́ oníwèé mẹ́wàa láti ọdún 1994 sí 1996 kí ó tó tẹ̀síwájú fún abala kejì ẹ̀kọ́ oníwèé mẹ́wàa ní Egbado College (tí ó ti di Yewa College) láti ọdún 1998 títí di oṣù kẹfà ọdún 2000 níbi tí ó ti ṣe ayẹyẹ ìkẹ́kọ̀ọ́ jáde gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ tí ó peregedé jùlọ nínú ìdíje àròkọ tí àwọn ọwọ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ Aionian ní ìpínlẹ̀ Ogun gbé kalẹ̀.[2] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àmì-ẹ̀yẹ Second Class Upper Degree nínú ẹ̀kọ́-ìmọ Òfin ìlú ní Fáfitì Jos ní oṣù kẹ́rin ọdún 2007. Akerele-Ogunsiji jẹ́ Mason Fed Mid Career Master nínú ẹ̀kọ́ ìṣàkóso ìlú ọ̀wọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ jáde ti Fáfitì Harvard ilé-ẹ̀kó ìjọba Kennedy.[3]
Ní ọdún 2017, Akerele-Ogunsiji darí àjọ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àgbáyé ti ilé-ẹ̀kó ìjọba Harvard Kennedy àti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìmọ̀-ẹ̀kọ́ Massachusetts (MIT) fún ìrìnàjò-ìmọ̀ ọlọ́sẹ̀ kan fún ìmọ̀-ọ̀tun àti sí àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba ní ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjírííà. Ìrìnàjò náà ni wọ́n ṣe lálàyé wí pé ó jẹ́ ọ̀nà tòótọ́ láti fi àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti gbogbo ẹ̀ka ìmọ̀ èkọ́ Harvard lápapọ̀ sójú-iṣé láti kẹ́kọ̀ọ́ síi nípa ìdàgbàsóke ìgbèríko àti ìmọ̀-tuntun, ìdíje nínú ètò ọrọ̀-ajé, ìjọba tiwantiwa àti àwọn ohun ìgbàlódé tó ń lọ nínú ètò ìṣèjọba ní ìpínlẹ̀ Èkó àti orílẹ̀-èdè Nàìjírííà."[10]
==Ẹbí rẹ̀==
Ní ọdún 2014, ó fẹ́ Adekunle Ogunsiji, onímọ̀ ẹ̀rọ, nínú ìgbeyàwó bòńkẹ́lẹ́ ní ilé ẹbí tí ó wà ní Ikeja, ní ìpínlẹ̀ Èkó.[11]
Akerele-Ogunsiji dá Passnownow sílẹ̀ ní ọdún 2012 pẹ̀lú èròǹgbà láti máa ran àwọn aláìní lọ́wọ́ àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọn ò láàǹfàní sí lílo àwọn ohun èlò ẹ̀kọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga, látoríi àwọn ẹ̀rọ alágbèéká.[7] Òun náà ló dá Printmagicng sílẹ̀, iléeṣẹ́ tí ń tẹ nǹkan jáde tí wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ fún wákàtí mẹ́rìnlélógún lówó tí ò ga ni lára lórí ẹ̀rọ ayélujára.[8][9]
Àwọn àtẹ̀jáde[edit]
Akerele-Ogunsiji ti ní àtẹ̀jáde àwọn ìwé àti pépà lóríṣiríṣi tí ó ti kọ lórí ètò ìdarí, àwọn ọ̀dọ́ àti ìdàgbàsókè okoòwò, pẹ̀lú àtẹ̀jáde àwọn ìwé wọ̀nyí:
Strate-Tricks: strategies and tricks, the winning formula for emerging businesses[12]We Have to Belong: Why the Poor Majority of my Rich Country cannot wait anymore tí wọ́n gbé jáde ní gbọ̀ngán àwọn adarí-ìlú, ní Harvard Kennedy School ní oṣù karùn-ún ọdún 2017.[13]
Her writings and interviews have been published in The Nation, the Nigerian Guardian, The Punch and This Day newspapers.
Awards, appointments and recognition[edit]
Selected as one of 101 Young African Leaders by the African Business Forum in 2007[14]Alumni of the Prestigious International Visitor Leadership Program of the United States Government[12]Recognition by Crans Montana Forum in Europe as a New Leader of Tomorrow [15]Recipient of This Day Awards for Nigeria's Women of Distinction [16][17]Young Entrepreneur of the Year 2011 of Success Digest Entrepreneurial Awards [18]Recipient of the 2011 Excellence Awards of the School of Media and Communication, Pan African University[19]Recipient of the 2008 Future Africa Awards Best Use of Advocacy Category and the Nigerian Youth Leadership Awards jointly organized by Leap Africa, International Youth Foundation and NOKIA.[20][21][22]One of the honorees’ of the Top 100 Young Leaders’ Recognition at the Nigeria's Centenary Celebrations by the Federal Government[14]Honoured by 234 GIVE, a Social Initiative that encourages Nigerians to donate to the adopted Charities and improve livelihoods for the less privileged [23]In May 2010, Toyosi was selected for the Nigeria Leadership Initiative's Future Leaders Fellowship. NLI is a member of the Aspen Global Leadership Network.[19][24]Member of The Right to Know Initiative, a Nonprofit focused on Human Rights and Open Data Issues and their social impact on Citizens in 2011 * Appointed the Youn
== Awọn itọkasi ==
[[Ẹ̀ka:Àwọn ènìyàn alààyè]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1983]]
[[Ẹ̀ka:Pages with unreviewed translations]]
2d6vuwy94n1f7dpo2kjbhq2njg3xb18
558475
558474
2022-08-20T12:42:39Z
Enitanade
24674
wikitext
text/x-wiki
{{Infobox person|name=Toyosi Akerele-Ogunsiji|image=Toyosi Akerele.jpg|birth_name=Toyosi Akerele|birth_date={{Birth date and age|1983|11|08|df=yes}}|birth_place=[[Lagos State]], [[Nigeria]]|occupation=onisowo iṣowo|website={{URL|www.toyosi.ng}}}}
'''Toyosi Akerele-Ogunsiji''' (wọ́n bí Oluwatoyosi Akerele, ní ọjọ́ kẹ́jo oṣù kọkànlá ọdún 1983) jẹ́ alákòóso àwọn olókoòwò-aládáni ti ìlu Nàìjírííà àti ọnímọ̀ nípa ìdàgbàsóke àwọn ènìyàn tí ọwọ́ ìja rẹ̀ lọ jákèjádò okoòwò-aládáni, ètò-ẹ̀kọ́, ìdàgbàsókè àwọn ọ̀dọ́ àti ìdarí ìlú. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti alákòóso àgbà ti Rise Networks, tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ aládàáni àti tìjọba tí ó ń ṣètò ìrànlọ́wọ́ owó fún àwọn ọ̀dọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjírííà.<ref>{{cite web|url=https://www.forbes.com/sites/mfonobongnsehe/2014/12/04/the-20-youngest-power-women-in-africa-2014/|title=The 20 Youngest Power Women In Africa 2014|first=Mfonobong|last=Nsehe|website=[[Forbes]]|publisher=}}</ref>
== Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ ==
Wọ́n bí Akerele-Ogunsiji sínú ẹbí James Ayodele àti Felicia Mopelola Akerele ní ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjírííà. Ó lọ si ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Ebun Oluwa Nursery and Primary School, ní Ọrẹgun ní ìpínlẹ̀ Èkó láti bẹ̀ ni ó ti darí sí Lagos State Model College Kankon ní Badagry, ní ìpínlẹ̀ Èkó fún abala kínní ẹ̀kọ́ oníwèé mẹ́wàa láti ọdún 1994 sí 1996 kí ó tó tẹ̀síwájú fún abala kejì ẹ̀kọ́ oníwèé mẹ́wàa ní Egbado College (tí ó ti di Yewa College) láti ọdún 1998 títí di oṣù kẹfà ọdún 2000 níbi tí ó ti ṣe ayẹyẹ ìkẹ́kọ̀ọ́ jáde gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ tí ó peregedé jùlọ nínú ìdíje àròkọ tí àwọn ọwọ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ Aionian ní ìpínlẹ̀ Ogun gbé kalẹ̀.<ref>{{cite web|url=https://stargist.com/life/inspirational_news/about-toyosi-akerele-toyosi-akerele-profile-toyosi-akerele-wikipedia-toyosi-akerele-biography/|title=Meet Toyosi Rise-Akerele, The Nigerian Entrepreneur Endorsed By Michelle Obama|date=4 May 2017|publisher=}}</ref>
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àmì-ẹ̀yẹ Second Class Upper Degree nínú ẹ̀kọ́-ìmọ Òfin ìlú ní Fáfitì Jos ní oṣù kẹ́rin ọdún 2007. Akerele-Ogunsiji jẹ́ Mason Fed Mid Career Master nínú ẹ̀kọ́ ìṣàkóso ìlú ọ̀wọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ jáde ti Fáfitì Harvard ilé-ẹ̀kó ìjọba Kennedy.<ref>{{cite web|url=https://www.naija.ng/1102673-meet-nigerian-lady-graduated-harvard-kennedy-school-alongside-40-exceptional.html#1102673|title=Meet Nigerian lady Toyosi Akerele-Ogunsiji who graduated from Harvard Kennedy School alongside 40 exceptional women (photos)|first=Simbiat|last=Ayoola|date=3 May 2017|publisher=}}</ref>
Ní ọdún 2017, Akerele-Ogunsiji darí àjọ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àgbáyé ti ilé-ẹ̀kó ìjọba Harvard Kennedy àti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìmọ̀-ẹ̀kọ́ Massachusetts (MIT) fún ìrìnàjò-ìmọ̀ ọlọ́sẹ̀ kan fún ìmọ̀-ọ̀tun àti sí àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba ní ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjírííà. Ìrìnàjò náà ni wọ́n ṣe lálàyé wí pé ó jẹ́ ọ̀nà tòótọ́ láti fi àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti gbogbo ẹ̀ka ìmọ̀ èkọ́ Harvard lápapọ̀ sójú-iṣé láti kẹ́kọ̀ọ́ síi nípa ìdàgbàsóke ìgbèríko àti ìmọ̀-tuntun, ìdíje nínú ètò ọrọ̀-ajé, ìjọba tiwantiwa àti àwọn ohun ìgbàlódé tó ń lọ nínú ètò ìṣèjọba ní ìpínlẹ̀ Èkó àti orílẹ̀-èdè Nàìjírííà."[10]
==Ẹbí rẹ̀==
Ní ọdún 2014, ó fẹ́ Adekunle Ogunsiji, onímọ̀ ẹ̀rọ, nínú ìgbeyàwó bòńkẹ́lẹ́ ní ilé ẹbí tí ó wà ní Ikeja, ní ìpínlẹ̀ Èkó.[11]
Akerele-Ogunsiji dá Passnownow sílẹ̀ ní ọdún 2012 pẹ̀lú èròǹgbà láti máa ran àwọn aláìní lọ́wọ́ àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọn ò láàǹfàní sí lílo àwọn ohun èlò ẹ̀kọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga, látoríi àwọn ẹ̀rọ alágbèéká.[7] Òun náà ló dá Printmagicng sílẹ̀, iléeṣẹ́ tí ń tẹ nǹkan jáde tí wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ fún wákàtí mẹ́rìnlélógún lówó tí ò ga ni lára lórí ẹ̀rọ ayélujára.
Àwọn àtẹ̀jáde[edit]
Akerele-Ogunsiji ti ní àtẹ̀jáde àwọn ìwé àti pépà lóríṣiríṣi tí ó ti kọ lórí ètò ìdarí, àwọn ọ̀dọ́ àti ìdàgbàsókè okoòwò, pẹ̀lú àtẹ̀jáde àwọn ìwé wọ̀nyí:
Strate-Tricks: strategies and tricks, the winning formula for emerging businesses[12]We Have to Belong: Why the Poor Majority of my Rich Country cannot wait anymore tí wọ́n gbé jáde ní gbọ̀ngán àwọn adarí-ìlú, ní Harvard Kennedy School ní oṣù karùn-ún ọdún 2017.[13]
Wọn ṣatẹjade awọn akọsilẹ ati ifọrọ-wanilẹnuwo rẹ ninu iwe-iroyin The nation, ati the Nigerian Guardian, The Punch ati This Day newspapers.
[[Ẹ̀ka:Àwọn ènìyàn alààyè]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1983]]
[[Ẹ̀ka:Pages with unreviewed translations]]
95o6mnbzla75x2332c7yhhw07de8v28